Yorùbá team

Àkójọ Àṣàyàn

Kaabo si Egbe WordPress Yoruba!

Egbe WordPress Yoruba je egbe ti o n risi iseÌtumọ̀ Yorùbá: ’tumo si sọfitiwia WordPress.org ni Ede Yoruba.

Eyi ni ibiti a ti n jiroro lori gbogbo awọn nkan ti o jọmọ titumọ WordPress ni Ede Yoruba. Darapo mo wa fun awọn imudojuiwọn gbogbogbo, awọn ijaÌtumọ̀ Yorùbá: ’bọ gbogbo, ati awọn ariyanjiyan.

Ṣayẹwo iwe itọnisọna wa lati kọ ẹkọ bi o ṣe le koÌtumọ̀ Yorùbá: ’pa.
https://make.wordpress.org/polyglots/handbook/

Yio wuwa ti iwo ba le darapo mowa lati KoÌtumọ̀ Yorùbá: ’pa!

Awọn ipade Ọsẹ

A ni awọn ipade ni gbogbo Ojo Aiku (Sunday) laago Mejo si mesan ale (8:00pm to 9:00pm) lori Slack ni ikanni #ìpàdé (iṣeto wa ni ẹgbẹ ẹgbẹ ti oju-iwe yii). O tun ni anfani lati bere awọn ibeere lori ikanni #ìbéèrè nigbakugba!

Kan siwa

O le kan si awa Ẹgbẹ to n see itumo si WordPress ni Ede Yoruba lori Slack. Ma jafara lati darapo mo wa nibi ti a ti n fi Ede Yoruba ba ara wa soro nipa WordPress

#meetings, #question

Ẹgbẹ WordPress Yoruba ni ipade…

Ẹgbẹ WordPress Yoruba ni ipade ni gbogbo Ọjọ Aiku (Sunday) laago mejo si mesan ale (8:00 PM Ìtumọ̀ Yorùbá: – 9:00 PM), lori ikanni #ipade ti Slack WordPress Yoruba tabi nipasẹ apejọ fidio.

A le ṣe atunṣe si Ofin yii ti isinmi (holiday) ba wa, tabi fun irorun ti gbogbo omo ẹgbẹ.

Maṣe gbagbe lati ṣe akiyesi awọn ọjọ wọnyi ninu kalẹnda rẹ ati pe ti o ko ba raye ni asiko naa, ranti lati se ayewo ipade na ninu ikanni #ipade lori slack.

📌 Awọn ipade wa ni sisi fun ẹnikẹni ti o nifẹ lati tumọ WordPress si Yoruba.

Awọn iṣura aaye

s
search
c
compose new post
r
reply
e
edit
t
go to top
j
go to the next post or comment
k
go to the previous post or comment
o
toggle comment visibility
esc
cancel edit post or comment
Please enable JavaScript to view this page properly.
Morty Proxy This is a proxified and sanitized view of the page, visit original site.